ResearchApp

...where knowledge is applied.

Category: Àló

Àló is simply storytelling in Yoruba language. Get set to be entertained and educated in the rich and beautiful language of SouthWest Nigeria.

Àlọ́ (1): Sọ́gbá ẹ

Àti kékeré ni mo ti gbọ́n ọgbọ́n pé ìwọ̀nba là á dá sí ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀, pàápàá tó bá ti jọ mọ tìjá. Ilé elérò ni a gbé dàgbà l’Èkó kó tó di wípé a kó padà s’ábúlé. Iya kan wa tó ń gbé nínú ọgbà wa nígbànáà. Ìyá ìbejì ni gbogbo wá mọ̀ ọ́ sí, àmọ́ (sugbon) ẹlẹ́dẹ̀ ń yájú lẹ́gbẹ́ màmá yìí ni, nipa ka bí ọmọ jọ.

Copyright HefTee Media and Event Consult 2015 Frontier Theme